May 2-8
1 SÁMÚẸ́LÌ 27-29
- Orin 71 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Sa 28:15—Ṣé Sámúẹ́lì ni Sọ́ọ̀lù “rí” nígbà tó lọ sọ́dọ̀ abẹ́mìílò? (w10 1/1 20 ¶5-6) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 27:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìyà—Jem 1:13. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 6) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Dúró Ṣinṣin Lójú Àtakò: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará láwọn ìbéèrè yìí: Kí la rí kọ́ látinú àpẹẹrẹ àwọn ará wa nígbà ìjọba Násì lórílẹ̀-èdè Jámánì? Kí ni àpẹẹrẹ àwọn ará wa ní Rọ́ṣíà ati Soviet Union àtijọ́ kọ́ wa? 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 02 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 94 àti Àdúrà