May 9-15
1 SÁMÚẸ́LÌ 30-31
- Orin 8 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Gbára Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ẹ̀dùn Ọkàn”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Sa 30:23, 24—Kí la rí kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí? (w05 3/15 24 ¶9) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 30:1-10 (th ẹ̀kọ́ 2) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Ìyà—1Jo 5:19. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 8) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fún ẹni tó ò ń wàásù fún ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kẹ́ ẹ sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 16) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Gbàdúrà Nígbà Gbogbo: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì béèrè àwọn ìbéèrè yìí lọ́wọ́ wọn: Kí nìdí tó fi yẹ kó o máa gbàdúrà sí Jèhófà? Àwọn ìgbà wo lo lè gbàdúrà sí i? Àwọn nǹkan wo lo lè gbàdúrà fún? 
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 03 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 95 àti Àdúrà