May 16-22
2 SÁMÚẸ́LÌ 1-3
- Orin 103 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Kí La Rí Kọ́ Látinú Orin Tí Dáfídì Pè Ní ‘Ọrun’?”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Sa 1:26—Kí nìdí tí Dáfídì fi pe Jónátánì ní “arákùnrin mi”? (it-1 369 ¶2) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 3:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Jẹ́ kẹ́ni náà mọ̀ pé ó lè kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 20) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 04 kókó 5 àti Àwọn Kan Sọ Pé (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ìfẹ́ . . . Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo”: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe—Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo. 
- “Ìfẹ́. . . Máa Ń Retí Ohun Gbogbo”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe—Ó Máa Ń Retí Ohun Gbogbo. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 04 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 2 àti Àdúrà