May 30–June 5
2 SÁMÚẸ́LÌ 7-8
- Orin 22 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Sa 8:2—Àsọtẹ́lẹ̀ wo ló ṣẹ nígbà tí Dáfídì ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù? (it-2 206 ¶2) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 7:1-17 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, kó o sì so ó mọ́ ohun kan tó ṣẹlẹ̀ lágbègbè yín. Fún onílé ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 13) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀, kó o sì so ó mọ́ ohun kan tó ṣẹlẹ̀ lágbègbè yín. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, kó o sì fún ẹni náà ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 18) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 04, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.) 
- “Máa Lo Àwọn Ohun Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Lágbègbè Rẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù”: (5 min.) Ìjíròrò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 06 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin Tuntun fún Àpéjọ Agbègbè Ọdún 2022 àti Àdúrà