June 6-12
2 SÁMÚẸ́LÌ 9-10
- Orin 124 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Dáfídì Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Sa 10:4, 5—Kí nìdí tí ohun tí Hánúnì ṣe fi jẹ́ ohun ìtìjú fáwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì? (it-1 266) 
- Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 9:1-13 (th ẹ̀kọ́ 12) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, ní ṣókí ẹ jíròrò “Bó o ṣe lè jàǹfààní púpọ̀ látinú ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí.” (th ẹ̀kọ́ 17) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 05 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 13) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe—Ó Ní Inú Rere: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Báwo ni Dáfídì ṣe fi inúure hàn sí Mefibóṣétì? Báwo la ṣe lè fi inúure àti ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn míì? 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 1 àti Àdúrà