September 5-11
1 ÀWỌN ỌBA 9–10
- Orin 10 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Ọb 10:10, 14—Kí ló fi hàn pé ìwọ̀n góòlù tí Bíbélì sọ pé Ọba Sólómọ́nì ní kì í ṣe àsọdùn? (w08 11/1 22 ¶4-6) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 10:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì—Sm 37:29. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fi ẹ̀kọ́ 01 nínú ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 13) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Wàá Rí Ìmọ̀ràn Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lórí Ìkànnì JW.ORG”: (8 min.) Ìjíròrò. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n lọ sórí Ìkànnì jw.org kí wọ́n lè rí ìmọ̀ràn Bíbélì tí wọ́n lè fi yanjú àwọn ìṣòro ojoojúmọ́. 
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (7 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 18 kókó 6-7 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́, àti ohun tó yẹ kó o ṣe 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 106 àti Àdúrà