September 12-18
1 ÀWỌN ỌBA 11-12
- Orin 137 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Fi Ọgbọ́n Yan Ẹni Tó O Máa Fẹ́”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Ọb 12:21-24—Kí la rí kọ́ nínú bí Ọba Rèhóbóámù ṣe tẹ̀ lé àṣẹ Jèhófà? (w18.06 14 ¶1-4) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 12:21-33 (th ẹ̀kọ́ 10) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Máa bá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan tó o bẹ̀rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ nìṣó, kẹ́ ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 01 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 11) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 8) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jèhófà Fẹ́ Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bó O Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó—Apá 3: Ṣírò Ohun Tó Máa Ná Ẹ. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 19 kókó 1-4 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 63 àti Àdúrà