September 19-25
1 ÀWỌN ỌBA 13-14
- Orin 21 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìtẹ́lọ́rùn, Ká sì Mọ̀wọ̀n Ara Wa?”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 1Ọb 14:13—Kí ni ẹsẹ Bíbélì yìí kọ́ wa nípa Jèhófà? (w10 7/1 29 ¶5) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 13:1-10 (th ẹ̀kọ́ 10) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 7) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Máa bá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan tó o bẹ̀rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ nìṣó, kẹ́ ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 01 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 9) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jẹ́ Kó Dá Ẹ Lójú Pé O Lè Fara Da Ìṣòro Àìlówó Lọ́wọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí—“Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí.” 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 19 kókó 5-6, kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 56 àti Àdúrà