October 31–November 6
2 ÀWỌN ỌBA 3-4
- Orin 151 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Gbé Ọmọ Rẹ”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Ọb 4:38—Àwọn wo ló ṣeé ṣe kó jẹ́ “àwọn ọmọ wòlíì”? (it-2 697 ¶2) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 3:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 17) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 20) 
- Àsọyé: (5 min.) w13 8/15 28-29—Àkòrí: Báwo Lo Ṣe Lè Fi Hàn Pé O Nírẹ̀lẹ̀ Bíi Ti Èlíṣà Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ? (th ẹ̀kọ́ 15) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ohun Tó Lè Tù Wá Nínú Kí Àjíǹde Tó Dé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 25 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 139 àti Àdúrà