November 21-27
2 ÀWỌN ỌBA 9-10
- Orin 126 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Ọb 10:29, 31—Kí la rí kọ́ látinú àṣìṣe Jéhù? (w11 11/15 5 ¶6-7) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 9:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, kó o sì fún un ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 12) 
- Àsọyé: (5 min.) w13 5/15 8-9 ¶3-6—Àkòrí: Jẹ́ Onítara Bíi Ti Jèhófà àti Jésù. (th ẹ̀kọ́ 16) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ—Fífi Nǹkan Falẹ̀: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló lè mú kẹ́nì kan máa fi nǹkan falẹ̀? Kí nìdí tí inú wa fi máa ń dùn tá ò bá fi nǹkan falẹ̀? 
- “Ohun Tí Kò Ní Jẹ́ Ká Máa Fi Nǹkan Falẹ̀”: (10 min.) Ìjíròrò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 28 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 19 àti Àdúrà