December 26–January 1
2 ÀWỌN ỌBA 20-21
- Orin 41 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Ọb 21:13—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà fi irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú díwọ̀n Jerúsálẹ́mù? (it-2 240 ¶1) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 21:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 4) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 08 kókó 6 (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Mi Ò Fọ̀rọ̀ Àdúrà Ṣeré. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 32 kókó 5-6, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 142 àti Àdúrà