ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 2
  • March 6-12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 6-12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 2

March 6-12

1 KÍRÓNÍKÀ 23-26

  • Orin 123 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Kr 25:7, 8​—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ bó ṣe ṣe pàtàkì tó pé ká máa kọrin ìyìn sí Jèhófà? (w22.03 22 ¶10)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Kr 23:21-32 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Àsọyé: (5 min.) w11 6/1 14-15​—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìjọsìn Àwọn Kristẹni? (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 101

  • “Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.

  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pe Àwọn Èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi ní Saturday, March 11: (5 min.) Ìjíròrò. Ṣàlàyé ohun tó wà nínú ìwé ìkésíni náà. Sọ ètò tí ìjọ ṣe nípa àkànṣe àsọyé àti Ìrántí Ikú Kristi, kẹ́ ẹ sì sọ ètò tí ìjọ ti ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 39 àti àlàyé ìparí ìwé 3

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 127 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́