March 27–April 2
2 KÍRÓNÍKÀ 5-7
- Orin 129 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Kr 6:29, 30—Kí nìdí tí àwọn ọ̀rọ̀ tí Sólómọ́nì sọ nínú àdúrà ẹ̀ fi lè tù wá nínú? (w10 12/1 11 ¶7) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 6:28-42 (th ẹ̀kọ́ 11) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó o pè, kó o wá dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bẹ́ ẹ ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 17) 
- Àsọyé: (5 min.) w93 2/1 31—Àkòrí: Tá Ò Bá Lè Lọ Síbi Ìrántí Ikú Kristi Fáwọn Ìdí Kan, Kí Ló Yẹ Ká Ṣe? (th ẹ̀kọ́ 18) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò. 
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 41 kókó 5 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́, àti ohun tó yẹ kó o ṣe 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 34 àti Àdúrà