June 5-11
2 KÍRÓNÍKÀ 30-31
- Orin 87 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - 2Kr 30:20—Kí la rí kọ́ látinú bí Jèhófà ṣe tẹ́tí sí Hẹsikáyà? (w18.09 6 ¶14-15) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 31:11-21 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 20) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹnì náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 18) 
- Àsọyé: (5 min.) w19.01 11-12 ¶13-18—Àkòrí: Bó O Ṣe Lè Fi Ìdáhùn Ẹ Yin Jèhófà Láwọn Ìpàdé. (th ẹ̀kọ́ 16) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Múra Ohun Tó O Máa Sọ ní Ìpàdé Sílẹ̀: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Tó bá ṣeé ṣe bi àwọn ọmọdé pé: Báwo lo ṣe lè múra sílẹ̀ láti dáhùn nípàdé? Kí ló lè mú kí inú ẹ dùn tí wọn ò bá tiẹ̀ pè ẹ́ nípàdé? 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 3 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 115 àti Àdúrà