July 24-30
NEHEMÁYÀ 1-2
- Orin 47 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Ne 2:4—Ṣé ìgbà àkọ́kọ́ rèé tí Nehemáyà máa gbàdúrà nípa ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀kọ́ wo la sì rí kọ́ nínú ohun tó ṣe? (w86 6/1 21) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ne 2:11-20 (th ẹ̀kọ́ 2) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 16) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 11 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ Kẹ́kọ̀ọ́ Jinlẹ̀ àti kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 11) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ṣé Jèhófà Máa Ń Dáhùn Àdúrà?: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà béèrè pé, Kí ni fídíò yìí kọ́ wa nípa àdúrà? 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 51 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 102 àti Àdúrà