August 28–September 3
NEHEMÁYÀ 12-13
- Orin 34 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Ne 13:10—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Léfì láwọn akọrin inú tẹ́ńpìlì, kí nìdí tí ẹsẹ Bíbélì yìí tún fi dárúkọ wọn lọ́tọ̀? (it-2 452 ¶9) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ne 12:27-39 (th ẹ̀kọ́ 2) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 16) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff kókó pàtàkì fún ẹ̀kọ́ 11, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 20) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- “Máa Fìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Bíi Ti Jèhófà”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 55 kókó 5 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 84 àti Àdúrà