September 11-17
Ẹ́SÍTÀ 3-5
- Orin 85 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Ẹst 4:12-16—Bíi ti Ẹ́sítà àti Módékáì, kí làwa náà lè ṣe ká lè jà fún òmìnira láti máa jọ́sìn Ọlọ́run láìsí ìdíwọ́? (kr 161 ¶14) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹst 3:1-12 (th ẹ̀kọ́ 2) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Ìjọba Ọlọ́run—Mt 14:19, 20. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 16) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 12 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 15) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ẹ́sítà Jẹ́ Onígboyà: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè yìí: Báwo lo ṣe lè fi hàn pé ó nígboyà bíi ti Ẹ́sítà? 
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 57 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 125 àti Àdúrà