October 2-8
JÓÒBÙ 1-3
- Orin 141 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Job 1:10—Báwo ni ohun tó wà nínú ẹsẹ yìí ṣe jẹ́ ká lóye ọ̀rọ̀ Jésù tó wà ní Mátíù 27:46? (w21.04 11 ¶9) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 3:1-26 (th ẹ̀kọ́ 12) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 9) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 20) 
- Àsọyé: (5 min.) w22.01 11-12 ¶11-14—Àkòrí: Jẹ́ Olùkọ́ Tó Mọ̀ọ̀yàn Kọ́ Bíi Ti Jémíìsì—Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O Sì Máa Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀. (th ẹ̀kọ́ 18) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Mo Rò Pé Mo ti Ní Gbogbo Nǹkan: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi wọ́n pé: Kí ló mú kí Arákùnrin Birdwell gbà pé òun “ti ní gbogbo nǹkan”? - Báwo lohun tó wà nínú Mátíù 6:33 ṣe ràn án lọ́wọ́? - Àwọn nǹkan míì wo lo tún rí kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ìdílé Birdwell? 
- “Máa Lo Abala Ìbẹ̀rẹ̀ Orí Ìkànnì JW.ORG Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù”: (5 min.) Ìjíròrò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 59 kókó 6 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (30 min.) 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 129 àti Àdúrà