October 30–November 5
JÓÒBÙ 11-12
- Orin 87 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Job 12:11—Báwo ni ìlànà tó wà nínú ẹsẹ yìí ṣe lè mú ká túbọ̀ máa fara balẹ̀ tẹ́tí sí àwọn míì? (w08 8/1 11 ¶5) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 12:1-25 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 13) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 12, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ọgbọ́n Ọlọ́run”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 1 ¶8-15, àti àpótí ojú ìwé 12 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 3 àti Àdúrà