November 6-12
JÓÒBÙ 13-14
- Orin 151 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Tí Èèyàn Bá Kú, Ṣé Ó Tún Lè Wà Láàyè?”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 13:1-28 (th ẹ̀kọ́ 12) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì—2Ti 3:16, 17. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 2) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 1 ìbéèrè 1-5 (th ẹ̀kọ́ 19) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Kí Kálukú Yín Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Gbóríyìn fáwọn ará fún bí wọ́n ṣe ń ya àwọn owó kan sọ́tọ̀ láti fi ti iṣẹ́ Jèhófà lẹ́yìn. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 1 ¶16-21 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 76 àti Àdúrà