November 20-26
JÓÒBÙ 18-19
- Orin 44 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Job 19:1, 2—Kí la rí kọ́ nínú bí Jóòbù ṣe fèsì nígbà tí “àwọn ọ̀rẹ́” rẹ̀ sọ àwọn ọ̀rọ̀ tó kó ẹ̀dùn ọkàn bá a? (w94 10/1 32) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 18:1-21 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé, kó o ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Àsọyé: (5 min.) w20.10 17 ¶10-11—Àkòrí: Gba Akẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Níyànjú Pé Kó Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Nínú Ìjọ. (th ẹ̀kọ́ 20) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni àwọn ọmọdé ṣe lè ran àwọn míì lọ́wọ́? - Kí lo lè ṣe láti ran àwọn míì lọ́wọ́? 
- “Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 2 ¶8-15 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 63 àti Àdúrà