December 18-24
JÓÒBÙ 28-29
- Orin 39 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?”: (10 min.) 
- Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.) - Job 29:24—Kí ni àpẹẹrẹ Jóòbù kọ́ wa? (g00 7/8 11 ¶3) 
- Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 28:1-28 (th ẹ̀kọ́ 5) 
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, ní ṣókí ẹ jíròrò “Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Yìí.” (th ẹ̀kọ́ 17) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 13 Kẹ́kọ̀ọ́ Jinlẹ̀ àti kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 6) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ohun Tí Mo Lè Ṣe Táá Jẹ́ Ká Túbọ̀ Lórúkọ Rere”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 3 ¶12-18 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) 
- Orin 50 àti Àdúrà