ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 January ojú ìwé 2
  • January 1-7

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 1-7
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 January ojú ìwé 2

JANUARY 1-7

JÓÒBÙ 32-33

Orin 102 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Eéwo bo Jóòbù látorí délẹ̀, Élíhù sì ń fara balẹ̀ tẹ́tí sí i.

Élíhù ń fara balẹ̀ tẹ́tí sí Jóòbù bó ṣe ń sọ ohun tó ń dùn ún

1. Máa Mára Tu Àwọn Tó Ní Ìdààmú Ọkàn

(10 min.)

Máa hùwà pẹ̀lẹ́ sáwọn èèyàn (Job 33:1; it-1 710)

Dípò kó o máa dá wọn lẹ́jọ́, ṣe ni kó o máa fọ̀rọ̀ wọn ro ara ẹ wò (Job 33:6, 7; w14 6/15 25 ¶8-10)

Bíi ti Élíhù, fara balẹ̀ tẹ́tí sí wọn, kó o sì ronú kó o tó sọ̀rọ̀ (Job 33:8-12, 17; w20.03 23 ¶17-18; wo àwòrán iwájú ìwé)

Arábìnrin kan ń fara balẹ̀ tẹ́tí sí obìnrin kan tó ń dá tọ́mọ bó ṣe ń sọ ohun tó ń kó ẹ̀dùn ọkàn bá a. Àwọn ọmọ ẹ̀ méjèèjì ń ṣeré nínú yàrá mí ì.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Job 33:25—Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé kò yẹ ká máa dara wa láàmú torí pé a fẹ́ dán láwọ̀ ju ọjọ́ orí wa lọ? (w13 1/15 19 ¶10)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Job 32:1-22 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Sọ Ohun Táwọn Èèyàn Nífẹ̀ẹ́ Sí—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 1-2.

5. Sọ Ohun Táwọn Èèyàn Nífẹ̀ẹ́ Sí—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 116

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 4, àpótí tó wà lójú ìwé 30

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 54 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́