ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 March ojú ìwé 13
  • April 22-28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 22-28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 March ojú ìwé 13

APRIL 22-28

SÁÀMÙ 32-33

Orin 103 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Wúwo

(10 min.)

Ọkàn Dáfídì ò balẹ̀ nígbà tó ń gbìyànjú láti bo ẹ̀ṣẹ̀ tó ṣeé ṣe kó dá pẹ̀lú Bátí-ṣébà mọ́lẹ̀ (Sm 32:3, 4; w93 3/15 9 ¶7)

Dáfídì jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, Jèhófà sì dárí jì í (Sm 32:5; cl 262 ¶8)

Ara tu Dáfídì nígbà tí Jèhófà dárí jì í (Sm 32:1; w01 6/1 30 ¶1)

Àwòrán: 1. Ìbànújẹ́ dorí ọ̀dọ́kùnrin kan kodò. 2. Ó ń gbàdúrà. 3. Ó lọ bá àwọn alàgbà méjì. 4. Inú ẹ̀ ń dùn torí pé ó ti pa dà ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà.

Tá a bá dá ẹ̀ṣẹ̀ tó wúwo, ó yẹ ká jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wa fún Jèhófà ká sì bẹ̀ ẹ́ pé kó dárí jì wá. Ó tún yẹ ká sọ fún àwọn alàgbà kí wọ́n lè ràn wá lọ́wọ́ láti pa dà ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà. (Jem 5:14-16) Èyí á jẹ́ ká lè rí ìtura gbà látọ̀dọ̀ Jèhófà.—Iṣe 3:19.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 33:6—Kí ni “èémí” ẹnu Jèhófà? (w06 5/15 20 ¶1)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 33:1-22 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀—Ohun Tí Pọ́ọ̀lù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 1-2.

5. Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 74

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 8 ¶22-24, àpótí ojú ìwé 67

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 39 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́