ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb25 January ojú ìwé 12-13
  • February 17-23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 17-23
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
mwb25 January ojú ìwé 12-13

FEBRUARY 17-23

ÒWE 1

Orin 88 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọba Sólómọ́nì ń gba ọmọ ẹ̀ nímọ̀ràn bí wọ́n ṣe jókòó síta.

Ọmọ Sólómọ́nì ń fetí sílẹ̀ bí bàbá ẹ̀ ṣe ń fìfẹ́ gbà á nímọ̀ràn

1. Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ta Lẹ Máa Fetí Sí?

(10 min.)

[Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Òwe.]

Jẹ́ ọlọgbọ́n kó o sì máa fetí sí àwọn òbí ẹ (Owe 1:8; w17.11 29 ¶16-17; wo àwòrán)

Má ṣe fetí sí àwọn tó ń ṣe ohun tí kò dáa (Owe 1:10, 15; w05 2/15 19-20 ¶11-12)

Ọ̀dọ́kùnrin kan wà níléèwé, àwọn ojúgbà ẹ̀ sì ń fúngun mọ́ ọn pé kó fi fóònù ṣe nǹkan kan tí ò dáa. Ó ń rò ó bóyá kóun ṣe nǹkan tí wọ́n sọ.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Owe 1:22—Tí Bíbélì bá lo ọ̀rọ̀ náà “òmùgọ̀,” àwọn wo ló sábà máa ń tọ́ka sí? (it-1 846)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Owe 1:1-23 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(2 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Ẹni náà fẹ́ bá ẹ jiyàn. (lmd ẹ̀kọ́ 6 kókó 5)

5. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(2 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Gba nọ́ńbà ẹni tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ ẹ. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 5)

6. Pa Dà Lọ

(2 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún ẹni náà ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)

7. Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn

(5 min.) lff ẹ̀kọ́ 16 kókó 6. Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ẹ kan ń ṣiyèméjì pé bóyá làwọn iṣẹ́ ìyanu tí Jésù ṣe wáyé lóòótọ́. Fi àpilẹ̀kọ kan lápá “Ṣèwádìí” ṣàlàyé fún un. (th ẹ̀kọ́ 3)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 89

8. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 22 ¶15-21

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 80 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́