Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Kò sí ohun tó lè dójú ti Sátánì tó pé ká tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ Jóòbù, kò sì sí ohun tó lè múnú Jèhófà dùn jùyẹn lọ!
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÀGBỌ́ NÍNÚ ỌLỌ́RUN > TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Tí èèyàn aláìpé méjì bá fẹ́ra wọn, oríṣiríṣi ìṣòro ló máa ń yọjú. Àmọ́ tí wọ́n bá ní sùúrù, ìdílé wọn á láyọ̀.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ > ÌGBÉYÀWÓ.