Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
A Pèsè Ìrànwọ́ Fáwọn Tí Àjálù Ṣẹlẹ̀ Sí
Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2020, àrùn Kòrónà àtàwọn àjálù míì mú kí nǹkan nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ará wa. Báwo la ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́?
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Tọkọtaya lè wà nínú yàrá kan náà síbẹ̀ kí wọ́n má bára wọn sọ̀rọ̀. Báwo ni tọkọtaya ṣe lè máa lo àkókò tí wọ́n fi wà pa pọ̀ lọ́nà tó dára jù lọ?
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ.