Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
AUGUST 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 3–NOVEMBER 6, 2022
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Kí Jóòbù lè mọ̀ pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ òun, Jèhófà jẹ́ kó mọ bí òun ṣe ń fìfẹ́ bójú tó àwọn nǹkan tóun dá (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 33, ìpínrọ̀ 10)