Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
A Pinnu Láti Jẹ́ Kí Nǹkan Díẹ̀ Tẹ́ Wa Lọ́rùn
Tẹ́lẹ̀, Madián àti Marcela máa ń ra gbogbo nǹkan tí wọ́n bá rí, ìyẹn jẹ́ kí wọ́n jẹ gbèsè tó pọ̀ gan-an, ó sì kó wọn lọ́kàn sókè. Àmọ́ ní báyìí tí wọ́n ti gbájú mọ́ kíkọ́ àwọn èèyàn ní òtítọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wọ́n ń láyọ̀ gan-an.
ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ
Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà?
Bíbélì sọ ohun tó o lè ṣe nígbà tí ojú ọjọ́ bá fa àjálù, bóyá kó tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó ṣẹlẹ̀.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Ohun Tó Yẹ Kí Àwọn Òbí Mọ̀ Nípa Jẹ́lé-Ó-Sinmi
Kẹ́ ẹ tó pinnu bóyá ẹ máa gbé ọmọ yín lọ sí jẹ́lé-ó-sinmi, ẹ kọ́kọ́ fara balẹ̀ ronú lórí àǹfààní tó wà níbẹ̀ àti àkóbá tó lè ṣe. Àwọn ìbéèrè tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kẹ́ ẹ lè pinnu ohun tó dáa jù fún ọmọ yín.