Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MARCH 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MAY 1–JUNE 4, 2023
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Kárí ayé, àwọn èèyàn lọ́mọdé àti lágbà ń ṣe àwọn àyípadà tó yẹ nígbèésí ayé wọn, wọ́n sì ń ṣèrìbọmi (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 11, ìpínrọ̀ 1-2)