Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 24: August 18-24, 2025
2 Ohun Tá A Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Tí Jékọ́bù Sọ Nígbà Tó Fẹ́ Kú—Apá Kìíní
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 25: August 25-31, 2025
8 Ohun Tá A Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Tí Jékọ́bù Sọ Nígbà Tó Fẹ́ Kú—Apá Kejì
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 26: September 1-7, 2025
14 Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 27: September 8-14, 2025
20 Ran Ẹni Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Mo Kọ́ Ọ̀pọ̀ Nǹkan Látọ̀dọ̀ Olùkọ́ Wa Atóbilọ́lá
32 Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́—Bó O Ṣe Lè Rántí Àwọn Ẹsẹ Bíbélì