Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 28: September 15-21, 2025
2 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Gbàmọ̀ràn Lọ́dọ̀ Àwọn Èèyàn?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 29: September 22-28, 2025
8 Bá A Ṣe Lè Gba Àwọn Èèyàn Nímọ̀ràn
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 30: September 29, 2025–October 5, 2025
14 Ṣé A Ṣì Lè Rí Nǹkan Kọ́ Nínú Àwọn Ẹ̀kọ́ Bíbélì Tá A Kọ́kọ́ Mọ̀?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 31: October 6-12, 2025
20 Ṣé O Mọ Béèyàn Ṣe Ń Nítẹ̀ẹ́lọ́rùn?
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—“Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”
32 Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́—Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ Kó O sì Máa Sọ Ohun Tó O Kọ́ Fáwọn Èèyàn