Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2026
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MARCH 2–APRIL 5, 2026
© 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́ ỌDÚN 2026:
“Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run.”—MÁT. 5:3.
A kì í ta ìwé yìí. Ó wà lára ohun tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé. Owó táwọn èèyàn fi ń ṣètìlẹ́yìn la fi ń ṣe gbogbo ohun tá à ń ṣe. Tó o bá fẹ́ ṣètìlẹ́yìn, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.