B9
Àwọn Agbára Ayé Tí Dáníẹ́lì Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Wọn
Bíi Ti Orí Ìwé
	| Bábílónì 607 Ṣ.S.K. Ọba Nebukadinésárì pa Jerúsálẹ́mù run | 
| Mídíà àti Páṣíà 539 Ṣ.S.K. Wọ́n ṣẹ́gun Bábílónì 537 Ṣ.S.K. Kírúsì pàṣẹ pé káwọn Júù pa dà sí Jerúsálẹ́mù | 
| Gíríìsì 331 Ṣ.S.K. Alẹkisáńdà Ńlá ṣẹ́gun Páṣíà | 
| Róòmù 63 Ṣ.S.K. Ó ṣàkóso ilẹ̀ Ísírẹ́lì 70 S.K. Ó pa Jerúsálẹ́mù run | 
| Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà 1914 sí 1918 S.K. Nígbà Ogun Àgbáyé Kìíní, Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso |