B15
Kàlẹ́ńdà Àwọn Hébérù
| NÍSÀN (ÁBÍBÙ) March—April | 14 Ìrékọjá 15-21 Búrẹ́dì Aláìwú 16 Fífi àwọn àkọ́so ṣe ọrẹ | Òjò àti yìnyín tó yọ́ mú kí odò Jọ́dánì kún sí i | Ọkà Báálì | 
| ÍÍYÀ (SÍFÌ) April—May | 14 Ìrékọjá lẹ́yìn àkókò rẹ̀ | Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn bẹ̀rẹ̀, kì í sí kùrukùru | Àlìkámà | 
| SÍFÁNÌ May—June | 6 Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (Pẹ́ńtíkọ́sì) | Ooru ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn, ojú ọjọ́ mọ́ kedere | Àlìkámà, àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́ | 
| TÁMÚSÌ June—July | Ooru pọ̀ sí i, ìrì púpọ̀ máa ń sẹ̀ ní agbègbè yìí | Àkọ́pọ́n èso àjàrà | |
| ÁBÌ July—August | Ìgbà tí ooru mú jù lọ | Àwọn èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn | |
| ÉLÚLÌ August—September | Ooru ṣì wà | Èso déètì, ọ̀pọ̀tọ́ àti àjàrà | |
| TÍṢÍRÌ (ÉTÁNÍMÙ) September—October | 1 Fífun kàkàkí 10 Ọjọ́ Ètùtù 15-21 Àjọyọ̀ Àtíbàbà 22 Àpéjọ ọlọ́wọ̀ | Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn parí, òjò àkọ́rọ̀ bẹ̀rẹ̀ | Títúlẹ̀ | 
| HÉṢÍFÁNÙ (BÚLÌ) October—November | Òjò winniwinni | Èso ólífì | |
| KÍSÍLÉFÌ November—December | 25 Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ | Òjò ń pọ̀ sí i, ìrì dídì, yìnyín bo òkè | Agbo ẹran kò sí níta mọ́ | 
| TÉBÉTÌ December—January | Ìgbà tí òtútù mú jù lọ, ìgbà òjò, yìnyín bo òkè | Ohun ọ̀gbìn ń hù | |
| ṢÉBÁTÌ January—February | Òtútù ò fi bẹ́ẹ̀ mú mọ́, òjò ṣì ń rọ̀ | Álímọ́ńdì yọ ìtànná | |
| ÁDÁRÌ February—March | 14, 15 Púrímù | Ààrá ń sán lemọ́lemọ́, yìnyín sì ń já bọ́ | Ọ̀gbọ̀ | 
| FÍÁDÀ March | Ìgbà méje ni wọ́n máa ń ní oṣù kẹtàlá láàárín ọdún 19 |