Ẹ́KÍSÓDÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń pọ̀ sí i ní Íjíbítì (1-7) 
- Fáráò ń fìyà jẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (8-14) 
- Àwọn agbẹ̀bí tó bẹ̀rù Ọlọ́run dá ẹ̀mí sí (15-22) 
 
-  2  - 
- Wọ́n bí Mósè (1-4) 
- Ọmọbìnrin Fáráò fi Mósè ṣe ọmọ rẹ̀ (5-10) 
- Mósè sá lọ sí Mídíánì, ó sì fẹ́ Sípórà (11-22) 
- Ọlọ́run gbọ́ bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ń kérora (23-25) 
 
-  3  - 
- Mósè àti igi ẹlẹ́gùn-ún tó ń jó (1-12) 
- Jèhófà sọ ìtúmọ̀ orúkọ Rẹ̀ (13-15) 
- Jèhófà fún Mósè ní ìtọ́ni (16-22) 
 
-  4  - 
- Iṣẹ́ àmì mẹ́ta tí Mósè máa ṣe (1-9) 
- Mósè ní òun ò kúnjú ìwọ̀n (10-17) 
- Mósè pa dà sí Íjíbítì (18-26) 
- Mósè àti Áárónì tún jọ pàdé (27-31) 
 
-  5  - 
- Mósè àti Áárónì lọ bá Fáráò (1-5) 
- Wọ́n túbọ̀ fìyà jẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (6-18) 
- Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá Mósè àti Áárónì lẹ́bi (19-23) 
 
-  6  - 
- Ọlọ́run tún ṣèlérí òmìnira ((1-13) 
- Ìlà ìdílé Mósè àti Áárónì (14-27) 
- Mósè tún máa lọ sọ́dọ̀ Fáráò (28-30) 
 
-  7  - 
- Jèhófà fún Mósè lókun (1-7) 
- Ọ̀pá Áárónì di ejò ńlá (8-13) 
- Ìyọnu 1: omi di ẹ̀jẹ̀ (14-25) 
 
-  8  
-  9  - 
- Ìyọnu 5: àwọn ẹran ọ̀sìn kú (1-7) 
- Ìyọnu 6: eéwo yọ sára èèyàn àti ẹranko (8-12) 
- Ìyọnu 7: òjò yìnyín (13-35) 
 
- 10  - 
- Ìyọnu 8: eéṣú (1-20) 
- Ìyọnu 9: òkùnkùn (21-29) 
 
- 11  
- 12  - 
- Ó fi Ìrékọjá lọ́lẹ̀ (1-28) 
- Ìyọnu 10: Ó pa àkọ́bí (29-32) 
- Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní ilẹ̀ náà (33-42) 
- Ìtọ́ni fún àwọn tó fẹ́ ṣe Ìrékọjá (43-51) 
 
- 13  - 
- Ti Jèhófà ni gbogbo àkọ́bí tó jẹ́ akọ (1, 2) 
- Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú (3-10) 
- Kí wọ́n ya gbogbo àkọ́bí tó jẹ́ akọ sọ́tọ̀ fún Ọlọ́run (11-16) 
- Ọlọ́run darí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gba ọ̀nà Òkun Pupa (17-20) 
- Ọwọ̀n ìkùukùu àti ọwọ̀n iná (21, 22) 
 
- 14  - 
- Ísírẹ́lì dé òkun (1-4) 
- Fáráò ń lépa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (5-14) 
- Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọdá Òkun Pupa (15-25) 
- Àwọn ará Íjíbítì rì sínú òkun (26-28) 
- Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà (29-31) 
 
- 15  - 
- Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọrin ìṣẹ́gun (1-19) 
- Míríámù fi orin dáhùn pa dà (20, 21) 
- Omi tó korò wá dùn (22-27) 
 
- 16  - 
- Àwọn èèyàn ń ráhùn torí oúnjẹ (1-3) 
- Jèhófà gbọ́ ìráhùn wọn (4-12) 
- Ó fún wọn ní ẹyẹ àparò àti mánà (13-21) 
- Kò sí mánà lọ́jọ́ Sábáàtì (22-30) 
- Wọ́n tọ́jú mánà fún ìrántí (31-36) 
 
- 17  - 
- Wọ́n ráhùn pé wọn ò rí omi mu ní Hórébù (1-4) 
- Omi jáde látinú àpáta (5-7) 
- Àwọn ọmọ Ámálékì gbógun ja Ísírẹ́lì, àmọ́ wọn ò borí (8-16) 
 
- 18  
- 19  - 
- Ní Òkè Sínáì (1-25) - 
- Ísírẹ́lì yóò di ìjọba àwọn àlùfáà (5, 6) 
- Ó sọ àwọn èèyàn di mímọ́ láti pàdé Ọlọ́run (14, 15) 
 
 
- 20  
- 21  
- 22  
- 23  - 
- Ìdájọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa tẹ̀ lé (1-19) 
- Áńgẹ́lì yóò máa darí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (20-26) 
- Gbígba ilẹ̀ àti ààlà (27-33) 
 
- 24  
- 25  
- 26  
- 27  
- 28  - 
- Àwọn aṣọ àlùfáà (1-5) 
- Éfódì (6-14) 
- Aṣọ ìgbàyà (15-30) 
- Aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá (31-35) 
- Láwàní àti àwo dídán (36-39) 
- Àwọn aṣọ míì tó jẹ́ ti àwọn àlùfáà (40-43) 
 
- 29  
- 30  - 
- Pẹpẹ tùràrí (1-10) 
- Ìkànìyàn àti owó ètùtù (11-16) 
- Bàsíà bàbà láti máa fi wẹ̀ (17-21) 
- Àkànṣe òróró àfiyanni (22-33) 
- Àwọn èròjà tùràrí mímọ́ (34-38) 
 
- 31  
- 32  
- 33  - 
- Ọlọ́run bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wí (1-6) 
- Àgọ́ ìpàdé ní ẹ̀yìn ibùdó (7-11) 
- Mósè fẹ́ rí ògo Jèhófà (12-23) 
 
- 34  - 
- Ó gbẹ́ àwọn wàláà òkúta míì (1-4) 
- Mósè rí ògo Jèhófà (5-9) 
- Ọlọ́run tún àwọn ọ̀rọ̀ májẹ̀mú náà sọ (10-28) 
- Ìtànṣán ń jáde lára awọ ojú Mósè (29-35) 
 
- 35  
- 36  
- 37  
- 38  
- 39  - 
- Wọ́n ṣe àwọn aṣọ àlùfáà (1) 
- Éfódì (2-7) 
- Aṣọ ìgbàyà (8-21) 
- Aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá (22-26) 
- Àwọn aṣọ míì tó jẹ́ ti àwọn àlùfáà (27-29) 
- Àwo wúrà (30, 31) 
- Mósè yẹ iṣẹ́ tí wọ́n ṣe sí àgọ́ ìjọsìn wò (32-43) 
 
- 40