LÉFÍTÍKÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  
-  3  
-  4  
-  5  - 
- Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ pàtó àti ọrẹ tí ẹni tó ṣẹ̀ máa mú wá (1-6) 
- Ọrẹ tí àwọn aláìní máa mú wá (7-13) 
- Ẹbọ ẹ̀bi fún ẹ̀ṣẹ̀ àìmọ̀ọ́mọ̀dá (14-19) 
 
-  6  
-  7  - 
- Ìtọ́ni nípa àwọn ọrẹ (1-21) 
- Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá tàbí ẹ̀jẹ̀ (22-27) 
- Ìpín àlùfáà (28-36) 
- Ọ̀rọ̀ ìparí nípa àwọn ọrẹ (37, 38) 
 
-  8  
-  9  
- 10  - 
- Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Jèhófà, ó sì pa Nádábù àti Ábíhù (1-7) 
- Ìlànà tí àwọn àlùfáà yóò máa tẹ̀ lé nípa jíjẹ àti mímu (8-20) 
 
- 11  
- 12  
- 13  
- 14  
- 15  
- 16  
- 17  - 
- Àgọ́ ìjọsìn, ibi tí wọ́n ti ń rúbọ (1-9) 
- Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ (10-14) 
- Ìlànà nípa àwọn ẹran tó ti kú (15, 16) 
 
- 18  
- 19  
- 20  - 
- Ìjọsìn Mólékì; ìbẹ́mìílò (1-6) 
- Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ sì bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí (7-9) 
- Ikú tọ́ sí àwọn oníṣekúṣe (10-21) 
- Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ lè wà ní ilẹ̀ náà (22-26) 
- Ikú tọ́ sí àwọn abẹ́mìílò (27) 
 
- 21  - 
- Kí àwọn àlùfáà jẹ́ mímọ́ kí wọ́n má sì di ẹlẹ́gbin (1-9) 
- Àlùfáà àgbà ò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ (10-15) 
- Àwọn àlùfáà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan lára (16-24) 
 
- 22  
- 23  
- 24  
- 25  - 
- Ọdún Sábáàtì (1-7) 
- Ọdún Júbílì (8-22) 
- Dídá ohun ìní pa dà (23-34) 
- Bí ẹ ṣe máa ṣe sí aláìní (35-38) 
- Òfin nípa ìfiniṣẹrú (39-55) 
 
- 26  
- 27  - 
- Ríra ohun téèyàn jẹ́jẹ̀ẹ́ rẹ̀ pa dà (1-27) 
- Àwọn ohun téèyàn yà sọ́tọ̀ pátápátá fún Jèhófà (28, 29) 
- Ríra ìdá mẹ́wàá pa dà (30-34)