NỌ́ŃBÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Wọ́n forúkọ àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun sílẹ̀ (1-46) 
- Àwọn ọmọ Léfì ò ní wọṣẹ́ ológun (47-51) 
- Bí wọ́n á ṣe pàgọ́ wọn létòlétò (52-54) 
 
-  2  
-  3  
-  4  - 
- Iṣẹ́ àwọn ọmọ Kóhátì (1-20) 
- Iṣẹ́ àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì (21-28) 
- Iṣẹ́ àwọn ọmọ Mérárì (29-33) 
- Àròpọ̀ iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ (34-49) 
 
-  5  - 
- Yíya àwọn aláìmọ́ sọ́tọ̀ (1-4) 
- Ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti sísan nǹkan dípò (5-10) 
- Lílo omi láti mọ̀ bóyá ẹnì kan ti ṣe àgbèrè (11-31) 
 
-  6  
-  7  
-  8  - 
- Áárónì tan fìtílà méje (1-4) 
- Wọ́n wẹ àwọn ọmọ Léfì mọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ (5-22) 
- Ọjọ́ orí àwọn ọmọ Léfì tó lè ṣiṣẹ́ (23-26) 
 
-  9  
- 10  - 
- Kàkàkí tí wọ́n fi fàdákà ṣe (1-10) 
- Wọ́n kúrò ní Sínáì (11-13) 
- Bí wọ́n ṣe máa tò tẹ̀ léra tí wọ́n bá ń lọ (14-28) 
- Mósè ní kí Hóbábù fi ọ̀nà han Ísírẹ́lì (29-34) 
- Àdúrà Mósè tí wọ́n bá ń tú àgọ́ ká (35, 36) 
 
- 11  - 
- Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run torí wọ́n ń ráhùn (1-3) 
- Wọ́n ń sunkún torí wọ́n fẹ́ jẹ ẹran (4-9) 
- Mósè wò ó pé òun ò kúnjú ìwọ̀n (10-15) 
- Jèhófà fi ẹ̀mí sára 70 àgbààgbà (16-25) 
- Ẹ́lídádì àti Médádì; Jóṣúà ń jowú torí Mósè (26-30) 
- Àwọn ẹyẹ àparò wá; Ọlọ́run fìyà jẹ wọ́n torí ìwọra wọn (31-35) 
 
- 12  
- 13  
- 14  - 
- Wọ́n fẹ́ pa dà sí Íjíbítì (1-10) 
- Jèhófà bínú; Mósè bá wọn bẹ̀bẹ̀ (11-19) 
- Ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn: 40 ọdún nínú aginjù (20-38) 
- Àwọn ọmọ Ámálékì ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (39-45) 
 
- 15  - 
- Òfin nípa ọrẹ (1-21) 
- Ọrẹ tí ẹni tó bá ṣèèṣì dẹ́ṣẹ̀ máa mú wá (22-29) 
- Ìyà tó máa jẹ ẹni tó bá mọ̀ọ́mọ̀ dẹ́ṣẹ̀ (30, 31) 
- Wọ́n pa ẹni tó rú òfin Sábáàtì (32-36) 
- Kí wọ́n máa ṣe wajawaja sí etí aṣọ wọn (37-41) 
 
- 16  
- 17  
- 18  - 
- Ojúṣe àwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì (1-7) 
- Ìpín àwọn àlùfáà (8-19) 
- Kí àwọn ọmọ Léfì máa gba ìdá mẹ́wàá, kí wọ́n sì máa san án (20-32) 
 
- 19  
- 20  
- 21  - 
- Wọ́n ṣẹ́gun ọba Árádì (1-3) 
- Ejò tí wọ́n fi bàbà ṣe (4-9) 
- Ísírẹ́lì lọ yí ká Móábù (10-20) 
- Wọ́n ṣẹ́gun Síhónì ọba àwọn Ámórì (21-30) 
- Wọ́n ṣẹ́gun Ógù ọba àwọn Ámórì (31-35) 
 
- 22  
- 23  
- 24  
- 25  
- 26  
- 27  
- 28  
- 29  
- 30  
- 31  
- 32  
- 33  
- 34  
- 35  - 
- Ìlú àwọn ọmọ Léfì (1-8) 
- Àwọn ìlú ààbò (9-34) 
 
- 36