ORIN SÓLÓMỌ́NÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
- Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍNÚ ÀGỌ́ ỌBA SÓLÓMỌ́NÌ (1:1–3:5) 
- Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍ JERÚSÁLẸ́MÙ (3:6–8:4) - 
- Àwọn ọmọbìnrin Síónì (6-11) - Sólómọ́nì àti àwọn tó ń tẹ̀ lé e 
 
 
 
- 
- Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ PA DÀ, Ó JẸ́ ADÚRÓTINI (8:5-14) - 
- Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (5a) - ‘Ta nìyí, tó fara ti olólùfẹ́ rẹ̀?’ 
 
- Ọ̀dọ́bìnrin (5b-7) - “Ìfẹ́ lágbára bí ikú” (6) 
 
- Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (8, 9) - “Tó bá jẹ́ ògiri, . . . àmọ́ tó bá jẹ́ ilẹ̀kùn, . . .” (9) 
 
- Ọ̀dọ́bìnrin (10-12) - “Ògiri ni mí” (10) 
 
- Olùṣọ́ àgùntàn (13) - ‘Jẹ́ kí n gbọ́ ohùn rẹ’ 
 
- Ọ̀dọ́bìnrin (14) - “Yára bí egbin” 
 
 
 
-