KÓLÓSÈ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìkíni (1, 2) 
- Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Kólósè (3-8) 
- Àdúrà pé kí wọ́n máa dàgbà sí i nípa tẹ̀mí (9-12) 
- Ipa àrà ọ̀tọ̀ tí Kristi kó (13-23) 
- Iṣẹ́ àṣekára tí Pọ́ọ̀lù ṣe fún ìjọ (24-29) 
 
-  2  - 
- Kristi, àṣírí mímọ́ Ọlọ́run (1-5) 
- Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn ẹlẹ́tàn (6-15) 
- Ohun gidi náà ni Kristi (16-23) 
 
-  3  
-  4  - 
- Ìmọ̀ràn fún àwọn ọ̀gá (1) 
- “Ẹ tẹra mọ́ àdúrà gbígbà” (2-4) 
- Ẹ máa fi ọgbọ́n bá àwọn tó wà lóde lò (5, 6) 
- Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (7-18)