Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀
Ṣé o gbà pé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì? Àbí o rò pé èrò àwọn èèyàn ni wọ́n kàn kọ síbẹ̀?
Ìwé ìròyìn “Jí!” yìí ṣàlàyé ẹ̀rí mẹ́ta tó mú kó dá wa lójú pé Ọlọ́run ló mí sí àwọn tó kọ Bíbélì.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.