Jẹ́ Alágbára!
ÒWÚRỌ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 38 àti Àdúrà 
- 10:00 Jèhófà Ló Ń Fún Wa Ní ‘Okun àti Agbára’ 
- 10:15 Jẹ́ Alágbára—Mú Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Fìdí Múlẹ̀ 
- 10:30 Jẹ́ Alágbára—Máa Fìtara Wàásù, Máa Kọ́ni, Kó O sì Máa Dáni Lẹ́kọ̀ọ́ 
- 10:55 Orin 7 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 Bí O Tilẹ̀ Jẹ́ Aláìlera, Jèhófà Á Sọ Ẹ́ Di Alágbára! 
- 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 Orin 79