Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé tá a bá gbàdúrà pé kí Jèhófà ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ aláìṣojo, ó máa dá wa lóhùn? (Sm. 138:3) 
- Báwo la ṣe lè jẹ́ aláìṣojo bí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run láyé àtijọ́? (Ìṣe 4:31) 
- Báwo la ṣe lè mọ́kàn le lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (1 Tẹs. 2:2) 
- Kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ aláìṣojo táwọn èèyàn bá ń fúngun mọ́ wa? (1 Pét. 2:21-23) 
- Ìbùkún wo làwa Kristẹni máa rí tá a bá ní ìgboyà tá ò sì ṣojo? (Héb. 10:35) 
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania