ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 15-17
“Ẹ Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé”
- Jésù ṣẹ́gun ayé nítorí pé kò fara wé ayé lọ́nàkọnà 
- Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù nílò ìgboyà kí wọ́n má bàa jẹ́ kí àwọn èèyàn tó wà nínú ayé yìí sọ wọ́n di bí wọ́n ṣe dà 
- Jésù ṣẹ́gun ayé, táwa náà bá ń ronú lórí àpẹẹrẹ tí Jésù fi lélẹ̀ fún wa, a máa ní ìgboyà tí àwa náà nílò láti lè ṣẹ́gun ayé