ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 46-47
Jèhófà Pèsè Oúnjẹ Lásìkò Ìyàn
Ìyàn tẹ̀mí mú gan-an nínú ayé lónìí. (Emọ 8:11) Àmọ́ Jèhófà ń lo Jésù Kristi láti pèsè ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ oúnjẹ tẹ̀mí tó ń ṣara lóore.
- Àwọn ìtẹ̀jáde tó dá lórí Bíbélì 
- Àwọn ìpàdé ìjọ 
- Àwọn àpéjọ àyíká àti agbègbè 
- Àwọn àtẹ́tísí 
- Àwọn fídíò 
- Ìkànnì JW.ORG 
- Ètò JW Broadcast 
Àwọn nǹkan wo ni mo ti pa tì kí n lè máa gbádùn gbogbo oúnjẹ tẹ̀mí tí Jèhófà ń pèsè?