ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 10
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Ni Ìpín Mi
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 10

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”

Àǹfààní iṣẹ́ ìsìn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ ni Jèhófà fún àwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì (Nọ 18:​6, 7)

Ẹ̀yà Léfì ò ní ilẹ̀ kankan tí wọ́n lè jogún, Jèhófà ni ogún wọn (Nọ 18:​20, 24; w11 9/15 13 ¶9)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń fún àwọn ọmọ Léfì àtàwọn àlùfáà ní ìdá mẹ́wàá (Nọ 18:​21, 26, 27; w11 9/15 7 ¶4)

Jèhófà ṣèlérí fáwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì pé òun á máa pèsè gbogbo ohun tí wọ́n nílò. Ó dájú pé Jèhófà ò ní fi àwa náà sílẹ̀ tá a bá yááfì àwọn nǹkan kan ká lè sìn ín.

Àwòrán: Jèhófà ń pèsè fún àwọn èèyàn rẹ̀. 1. Arábìnrin kan ń fi owó sínú àpò ìwé. 2. Ó fi àpò ìwé náà há ẹnu ọ̀nà òbí anìkàntọ́mọ kan. 3. Òbí anìkàntọ́mọ kan gbá ọmọ rẹ̀ mọ́ra, ó sì ń wo owó tó wà nínú àpò ìwé.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́