ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 7
  • Kí Lo Máa Yááfì fún Jèhófà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Lo Máa Yááfì fún Jèhófà?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí La Rí Kọ́ Látinú Orin Tí Dáfídì Pè Ní “Ọrun”?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ọlọ́run Onídàájọ́ Òdodo Ni Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Gbára Lé Jèhófà fún Ìrànlọ́wọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kí Lo Máa Yááfì fún Jèhófà?

Jèhófà pàṣẹ pé kí Dáfídì kọ́ pẹpẹ kan ní ibi ìpakà Áráúnà (2Sa 24:18)

Áráúnà sọ pé òun máa fún Dáfídì ní ilẹ̀ àtàwọn ẹran tó máa fi rúbọ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ (2Sa 24:21-23)

Dáfídì sọ pé òun ò ní rú ẹbọ tí kò ná òun ní nǹkan kan sí Jèhófà (2Sa 24:24, 25; it-1 146)

Fọ́tò: Àwọn ọ̀nà tá a lè gbà fún Jèhófà ní nǹkan. 1. Àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin ń ṣèrànwọ́ láti kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba kan. 2. Arábìnrin àgbàlagbà kan ń fowó sínú àpótí ọrẹ. 3. Tọkọtaya kan ń wàásù níbi àtẹ ìwé. 4. Àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin ń pèsè ìrànwọ́ fáwọn tí àjálù bá.

Inú Jèhófà máa ń dùn tá a bá fínnúfíndọ̀ yọ̀ǹda àkókò wa, okun wa àtàwọn nǹkan ìní wa fún ire Ìjọba náà. (w12 1/15 18 ¶8) Àwọn nǹkan wo lo lè fi ṣe àfojúsùn ẹ kó o lè túbọ̀ máa rú “ẹbọ ìyìn” sí Jèhófà?​—Heb 13:15.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́