ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 12
  • Fara Wé Èlíṣà Tí Wọ́n Bá Ń Dá Ẹ Lẹ́kọ̀ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Fara Wé Èlíṣà Tí Wọ́n Bá Ń Dá Ẹ Lẹ́kọ̀ọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Èlíṣà Rí Kẹ̀kẹ́ Ẹṣin Oníná—Ṣé Ìwọ Náà Rí I?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Àpẹẹrẹ Ìfara-Ẹni-Rúbọ àti Ìdúróṣinṣin
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Bí Àwọn Alàgbà Ṣe Ń Kọ́ Àwọn Míì Kí Wọ́n Lè Tóótun
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 12
Èlíṣà ń wò ó bí Èlíjà ṣe ń fi aṣọ rẹ̀ pín Odò Jọ́dánì sí méjì.

Èlíṣà ń wo Èlíjà bó ṣe ń ṣiṣẹ́ ìyanu kan

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Fara Wé Èlíṣà Tí Wọ́n Bá Ń Dá Ẹ Lẹ́kọ̀ọ́

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àwọn Ọba Kejì.]

Èlíṣà ń wo bí Èlíjà ṣe ṣiṣẹ́ ìyanu kan (2Ọb 2:8; w15 4/15 13 ¶15; wo àwòrán iwájú ìwé)

Èlíṣà nírẹ̀lẹ̀, bí Èlíjà ṣe kọ́ ọ gẹ́lẹ́ ló ṣe (2Ọb 2:13, 14; w15 4/15 13 ¶16)

Alàgbà kan ń tẹ́tí sí arákùnrin kan tó ń múra àsọyé sílẹ̀. Alàgbà náà ṣí ìwé “Kíkọ́ni.”

Àwọn alàgbà ni Jèhófà fún ní ojúṣe láti máa dá àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́ nínú ìjọ. (2Ti 2:2) Táwọn alàgbà bá fẹ́ dá ẹ lẹ́kọ̀ọ́, rí i pé o wà ní ìmúratán, o ṣeé fọkàn tán, ó sì nírẹ̀lẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́