ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 8
  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Ìsapá Tá A Bá Fi Gbogbo Ọ̀kan Ṣe

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Ìsapá Tá A Bá Fi Gbogbo Ọ̀kan Ṣe
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹgbẹ́ Búburú Ò Jẹ́ Kí Jèhóáṣì Sin Jèhófà Mọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ọgbọ́n Táwọn Alátakò Máa Ń Dá Kí Wọ́n Lè Kó Ìrẹ̀wẹ̀sì Bá Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 8
Èlíṣà wà ní ìdùbúlẹ̀ àìsàn bó ṣe ń fún Ọba Jèhóáṣì ní ìtọ́ni. Jèhóáṣì di ọfà mẹ́rin mú.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Bù Kún Ìsapá Tá A Bá Fi Gbogbo Ọ̀kan Ṣe

Èlíṣà sọ fún Ọba Jèhóáṣì pé kó ṣe ohun kan tó ṣàpẹẹrẹ bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe máa ṣẹ́gun àwọn ará Síríà (2Ọb 13:15-18)

Torí pé Jèhóáṣì ò fi gbogbo ọ̀kan ẹ̀ sí ohun tí Èlíṣà ní kó ṣe, àṣeyọrí tó ṣe ò tó nǹkan (2Ọb 13:19; w10 4/15 26 ¶11)

Jèhófà máa ń bù kún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó ń wá a tọkàntọkàn (Heb 11:6; w13 11/1 11 ¶5-6)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ó hàn pé tọkàntọkàn ni mo nífẹ̀ẹ́ Jèhófà tó bá dọ̀rọ̀ ọwọ́ tí mo fi mú àwọn nńkan bí iṣẹ́ ìwàásù, Bíbélì kíkà àti wíwá sípàdé?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́