Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé “Àwọn ọmọ wòlíì” ṣeé ṣe kó máa tọ́ka sí ilé ẹ̀kọ́ tí àwọn wòlíì ti ń gba ìtọ́ni tàbí ẹgbẹ́ tó jẹ́ ti àwọn wòlíì.